Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 43:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nisinsinyii, Jakọbu,gbọ́ nǹkan tí OLUWA ẹlẹ́dàá rẹ wí,Israẹli, gbọ́ ohun tí ẹni tí ó dá ọ sọ.Ó ní, “Má bẹ̀rù, nítorí mo ti rà ọ́ pada;mo ti pè ọ́ ní orúkọ rẹ, èmi ni mo ni ọ́.

Ka pipe ipin Aisaya 43

Wo Aisaya 43:1 ni o tọ