Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 42:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ta ni afọ́jú, bíkòṣe iranṣẹ mi?Ta sì ni adití, bíkòṣe ẹni tí mo rán níṣẹ́?Ta ni ó fọ́jú tó ẹni tí mo yà sọ́tọ̀,tabi ta ni ojú rẹ̀ fọ́ tó ti iranṣẹ OLUWA?

Ka pipe ipin Aisaya 42

Wo Aisaya 42:19 ni o tọ