Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 40:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé o kò tíì mọ̀,o kò sì tíì gbọ́pé Ọlọrun ayérayé ni OLUWA,Ẹlẹ́dàá gbogbo ayé.Kì í rẹ̀ ẹ́, bẹ́ẹ̀ ni agara kì í dá a.Àwámárìídìí ni òye rẹ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 40

Wo Aisaya 40:28 ni o tọ