Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 39:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Hesekaya dá Aisaya lóhùn, ó ní, “Ohun rere ni OLUWA sọ.” Ó sọ bẹ́ẹ̀ nítorí ó rò pé alaafia ati ìfọ̀kànbalẹ̀ yóo wà ní àkókò tòun.

Ka pipe ipin Aisaya 39

Wo Aisaya 39:8 ni o tọ