Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 39:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, ‘Ọjọ́ ń bọ̀ tí a óo ru gbogbo ohun tí ó wà láàfin rẹ lọ sí Babiloni, ati gbogbo ìṣúra tí àwọn baba ńlá rẹ ti kó jọ títí di òní. Kò ní ku nǹkankan.’ OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 39

Wo Aisaya 39:6 ni o tọ