Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 39:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò náà Merodaki Baladani ọmọ Baladani, ọba Babiloni, fi ìwé ati ẹ̀bùn rán àwọn ikọ̀ kan sí Hesekaya, nítorí ó gbọ́ pé ara rẹ̀ kò ti dá tẹ́lẹ̀ ṣugbọn ara rẹ̀ ti wá le.

Ka pipe ipin Aisaya 39

Wo Aisaya 39:1 ni o tọ