Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 38:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Òun óo mú kí òjìji oòrùn ìrọ̀lẹ́ pada sẹ́yìn ní àtẹ̀gùn mẹ́wàá lórí àtẹ̀gùn Ahasi. Oòrùn bá yí pada nítòótọ́, òjìji sì pada sẹ́yìn ní àtẹ̀gùn mẹ́wàá tí ó ti sọ tẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 38

Wo Aisaya 38:8 ni o tọ