Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 38:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkàn mi ń ṣe hílàhílo bí ẹyẹ aláàpáǹdẹ̀dẹ̀ ati ẹyẹ àkọ̀,mò ń ké igbe arò bí àdàbà.Mo wòkè títí ojú ń ro mí,ara ń ní mí, OLUWA, nítorí náà ṣe ààbò mi.

Ka pipe ipin Aisaya 38

Wo Aisaya 38:14 ni o tọ