Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 37:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ibẹ̀ ni àwọn kan ti ròyìn fún ọba Asiria pé, Tirihaka ọba Etiopia ń bọ̀ wá gbógun tì í. Nígbà tí ó gbọ́, ó rán ikọ̀ lọ bá Hesekaya, ó ní:

Ka pipe ipin Aisaya 37

Wo Aisaya 37:9 ni o tọ