Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 37:26 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣé o kò tíì gbọ́ pé láti ìgbà pípẹ́,ni mo ti pinnu ohun tí mò ń mú ṣẹ nisinsinyii?Láti ayébáyé ni mo ti ṣètò rẹ̀,pé kí o wó ìlú olódi palẹ̀,kí ó di òkítì àlàpà.

Ka pipe ipin Aisaya 37

Wo Aisaya 37:26 ni o tọ