Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 36:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Eliakimu, ọmọ Hilikaya tí ó jẹ́ alákòóso ààfin ati Ṣebina, akọ̀wé ilé ẹjọ́, ati Joa, ọmọ Asafu, akọ̀wé ààfin wá sọ́dọ̀ Hesekaya pẹlu àwọn ti aṣọ wọn tí wọ́n ti fàya láti fi ìbànújẹ́ wọn hàn, wọ́n sì sọ ohun tí Rabuṣake wí fún un.

Ka pipe ipin Aisaya 36

Wo Aisaya 36:22 ni o tọ