Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 36:16 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ má fetí sí ọ̀rọ̀ Hesekaya; nítorí ọba Asiria ní kí ẹ bá òun ṣe àdéhùn alaafia kí ẹ jáde tọ òun wá. Bí ẹ bá ṣe bẹ́ẹ̀, olukuluku yín ni yóo máa jẹ èso àjàrà ati èso ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀, olukuluku yín yóo sì máa mu omi ninu kànga rẹ̀;

Ka pipe ipin Aisaya 36

Wo Aisaya 36:16 ni o tọ