Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 35:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ sọ fún àwọn tí àyà wọn ń já pé:“Ẹ ṣe ara gírí, ẹ má bẹ̀rù.Ẹ wò ó! Ọlọrun yín óo wá pẹlu ẹ̀san,ó ń bọ̀ wá gbẹ̀san gẹ́gẹ́ bí Ọlọrun;ó ń bọ̀ wá gbà yín là.”

Ka pipe ipin Aisaya 35

Wo Aisaya 35:4 ni o tọ