Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 34:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Oòrùn, òṣùpá, ati àwọn ìràwọ̀ yóo gbọ̀n dànùa óo ká awọsanma bí ẹni ká ìwé.Oòrùn, òṣùpá, ati àwọn ìràwọ̀ yóo jábọ́bí ewé tií rẹ̀ sílẹ̀ lára ìtàkùn àjàrà,àní, bí ewé tií wọ́ dànù lórí igi ọ̀pọ̀tọ́.

Ka pipe ipin Aisaya 34

Wo Aisaya 34:4 ni o tọ