Ó ti ṣẹ́ gègé fún wọn,ó ti fi okùn wọ̀n ọ́n kalẹ̀ fún wọn.Àwọn ni wọn óo ni ín títí lae,wọn óo sì máa gbé ibẹ̀ láti ìrandíran.