Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 33:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀rù ń ba àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ tí ó wà ní Sioni;ìjayà mú àwọn ẹni tí kò mọ Ọlọrun.Ta ni ninu wa ló lè gbé inú iná ajónirun?Ta ni ninu wa ló lè gbé inú iná àjóòkú?

Ka pipe ipin Aisaya 33

Wo Aisaya 33:14 ni o tọ