Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 3:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwà àgàbàgebè wọn ń takò wọ́n;wọ́n ń polongo ẹ̀ṣẹ̀ wọn bíi ti Sodomu:Wọn kò fi bò rárá.Ègbé ni fún wọn,nítorí pé àwọn ni wọ́n mú ibi wá sórí ara wọn.

Ka pipe ipin Aisaya 3

Wo Aisaya 3:9 ni o tọ