Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 3:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ náà, ẹni tí wọn sọ pé kí ó jẹ olórí yóo kígbe pé,“Èmi kò ní jẹ oyè alátùn-únṣe.N kò ní oúnjẹ nílébẹ́ẹ̀ ni kò sí aṣọ.Ẹ má fi mí ṣe olórí yín.”

Ka pipe ipin Aisaya 3

Wo Aisaya 3:7 ni o tọ