Nítorí náà ẹ má ṣe yẹ̀yẹ́,kí á má baà so ẹ̀wọ̀n yín le.Nítorí mo ti gbọ́ ìkéde ìparun,tí OLUWA àwọn ọmọ ogun pinnu láti mú wá sórí ilẹ̀ ayé.