Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 28:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Majẹmu tí ẹ bá ikú dá yóo wá di òfo,àdéhùn yín pẹlu ibojì yóo sì di asán.Nígbà tí jamba bá ń ṣẹlẹ̀ káàkiri,yóo máa dé ba yín.

Ka pipe ipin Aisaya 28

Wo Aisaya 28:18 ni o tọ