Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 26:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ní àkókò náà,orin tí wọn óo máa kọ ní ilẹ̀ Juda ni pé:“A ní ìlú tí ó lágbára,ó fi ìgbàlà ṣe odi ati ibi ààbò.

2. Ẹ ṣí ìlẹ̀kùn ibodè,kí orílẹ̀-èdè olódodo, tí ń ṣe òtítọ́ lè wọlé.

Ka pipe ipin Aisaya 26