Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 25:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn óo máa wí ní ọjọ́ náà pé, “Ọlọrun wa nìyí; a ti ń dúró dè é kí ó lè gbà wá, OLUWA nìyí; òun ni a ti ń dúró dè. Ẹ jẹ́ kí á máa yọ̀, kí inú wa sì dùn nítorí ìgbàlà rẹ̀.”

Ka pipe ipin Aisaya 25

Wo Aisaya 25:9 ni o tọ