Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 20:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn ọdún mẹta, OLUWA dáhùn pé, “Bí Aisaya, iranṣẹ mi, ti rìn ní ìhòòhò tí kò sì wọ bàtà fún ọdún mẹta yìí, jẹ́ àmì ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ sí ilẹ̀ Ijipti ati ilẹ̀ Kuṣi:

Ka pipe ipin Aisaya 20

Wo Aisaya 20:3 ni o tọ