Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 2:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ iwájúòkè ilé OLUWA yóo fi ìdí múlẹ̀, gẹ́gẹ́ bí òkè tí ó ga jùlọ,a óo sì gbé e ga ju àwọn òkè yòókù lọ.Gbogbo orílẹ̀-èdè yóo wá sibẹ.

Ka pipe ipin Aisaya 2

Wo Aisaya 2:2 ni o tọ