Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 2:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan yóo sá sinu ihò àpáta,wọn yóo sì wọ inú ihò ilẹ̀ lọ,nígbà tí wọ́n bá ń sá fún ibinu OLUWA,ati ògo ọlá ńlá rẹ̀nígbà tí ó bá dìde láti mi ayé tìtì.

Ka pipe ipin Aisaya 2

Wo Aisaya 2:19 ni o tọ