Gbogbo odò wọn yóo máa rùn,gbogbo àwọn odò tí ó ṣàn wọ odò Naili ní Ijipti,ni yóo fà, tí yóo sì gbẹ:Gbogbo koríko odò yóo rà.