Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 19:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Tó bá di ìgbà náà, ọ̀nà tí ó tóbi kan yóo wà láti Ijipti dé Asiria–àwọn ará Asiria yóo máa lọ sí Ijipti, àwọn ará Ijipti yóo sì máa lọ sí Asiria; àwọn ará Ijipti yóo máa jọ́sìn pẹlu àwọn ará Asiria.

Ka pipe ipin Aisaya 19

Wo Aisaya 19:23 ni o tọ