Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 19:21 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA yóo sọ ara rẹ̀ di mímọ̀ fún àwọn ará Ijipti, wọn óo sì mọ OLUWA nígbà náà. Wọ́n yóo máa sin OLUWA pẹlu ẹbọ ati ẹbọ sísun; wọn óo jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún OLUWA, wọn yóo sì mú ẹ̀jẹ́ náà ṣẹ.

Ka pipe ipin Aisaya 19

Wo Aisaya 19:21 ni o tọ