Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 19:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sí nǹkankan tí ẹnìkan lè ṣe fún Ijipti,kì báà jẹ́ ọlọ́lá tabi mẹ̀kúnnù,kì báà jẹ́ eniyan pataki tabi ẹni tí kò jẹ́ nǹkan.

Ka pipe ipin Aisaya 19

Wo Aisaya 19:15 ni o tọ