Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 13:11 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fìyà jẹ ayé nítorí iṣẹ́ ibi rẹ̀,n óo sì jẹ àwọn ìkà níyà nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn.N óo fòpin sí àṣejù àwọn onigbeeraga,n óo rẹ ìgbéraga àwọn tí kò lójú àánú sílẹ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 13

Wo Aisaya 13:11 ni o tọ