Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 12:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó! Ọlọrun ni olùgbàlà mi,n óo gbẹ́kẹ̀lé eẹ̀rù kò sì ní bà mí,nítorí pé OLUWA Ọlọrun ni agbára mi, ati orin mi,òun sì ni Olùgbàlà mi.”

Ka pipe ipin Aisaya 12

Wo Aisaya 12:2 ni o tọ