Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 11:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ náà, OLUWA yóo na ọwọ́ rẹ̀ lẹẹkeji, yóo ra àwọn eniyan rẹ̀ yòókù pada ní oko ẹrú, láti Asiria, ati Ijipti, láti Patosi ati Etiopia, láti Elamu ati Ṣinari, láti Amati ati àwọn erékùṣù òkun.

Ka pipe ipin Aisaya 11

Wo Aisaya 11:11 ni o tọ