Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 10:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo rán wọn láti gbógun ti àwọn tí kò mọ Ọlọrun,ati àwọn eniyan tí wọ́n bá mú mi bínú.Pé kí wọ́n kó wọn lẹ́rù.Kí wọ́n kó wọn lẹ́rúkí wọ́n tẹ̀ wọ́n mọ́lẹ̀ bíi ẹrọ̀fọ̀tí à ń tẹ̀ mọ́lẹ̀ níta gbangba.

Ka pipe ipin Aisaya 10

Wo Aisaya 10:6 ni o tọ