Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 10:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Àwọn tí ń ṣe òfin tí kò tọ́ gbé!Bẹ́ẹ̀ sì ni àwọn akọ̀wé, tí ń kọ̀wé láti ni eniyan lára;

2. wọ́n ń dínà ìdájọ́ òdodo fún àwọn aláìní,wọn kò sì jẹ́ kí àwọn talaka ààrin àwọn eniyan mi rí ẹ̀tọ́ wọn gbà,kí wọ́n lè sọ àwọn opó di ìkógun.

3. Kí ni ẹ óo ṣe lọ́jọ́ ìjìyà yíntí ìparun bá dé láti òkèèrè?Ta ni ẹ óo sá tọ̀ lọ fún ìrànlọ́wọ́?Níbo ni ẹ óo kó ọrọ̀ yín sí?

Ka pipe ipin Aisaya 10