Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 1:30-31 BIBELI MIMỌ (BM)

30. Nítorí pé ẹ óo dàbí igi oaku tí ó wọ́wé,ati bí ọgbà tí kò lómi.

31. Alágbára yóo dàbí ògùṣọ̀,iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ bí ìṣáná.Àwọn mejeeji ni yóo jóná pọ̀,kò sì ní sí ẹni tí yóo lè pa iná náà.

Ka pipe ipin Aisaya 1