Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Máa gbọ́, ìwọ ọ̀run,sì fetí sílẹ̀, ìwọ ayéNítorí pé OLUWA ń sọ̀rọ̀Ó ní, “Lẹ́yìn tí mo bọ́ àwọn ọmọ,tí mo tọ́ wọn dàgbà tán,ọ̀tẹ̀ ni wọ́n dì sí mi.

Ka pipe ipin Aisaya 1

Wo Aisaya 1:2 ni o tọ