Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 1:11 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní,“Kí ni gbogbo ẹbọ yín jámọ́ fún mi?Àgbò tí ẹ fi ń rú ẹbọ sísun sí mi ti tó gẹ́ẹ́;bẹ́ẹ̀ náà sì ni ọ̀rá ẹran àbọ́pa.N kò ní inú dídùn sí ẹ̀jẹ̀ mààlúù tabi ti ọ̀dọ́ aguntan tabi ti òbúkọ.

Ka pipe ipin Aisaya 1

Wo Aisaya 1:11 ni o tọ