Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Títù 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ wọ̀nyìí. Mo sì fẹ́ kí ó ṣe ìtẹnumọ́ rẹ̀, kí àwọn tí wọ́n ti gbàgbọ́ nínú Olúwa le kíyèsí láti máa fi ara wọn jìn fún iṣẹ́ rere. Nǹkan wọ̀nyìí dára, wọ́n sì jẹ èrè fún gbogbo ènìyàn.

Ka pipe ipin Títù 3

Wo Títù 3:8 ni o tọ