Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Títù 3:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn tí ń bẹ lọ́dọ̀ mi kí ọ. Bá mi kí àwọn tí ó fẹ́ wa nínú ìgbàgbọ́. Kí oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run wà pẹ̀lú gbogbo yín. Àmín.

Ka pipe ipin Títù 3

Wo Títù 3:15 ni o tọ