Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Títù 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rán àwọn ènìyàn náà létí láti máa tẹríba fún ìjọba àti àwọn aláṣẹ. Kí wọn ṣe ìgbọ́ràn nígbà gbogbo, kí wọn sì múra fún iṣẹ́ rere gbogbo.

Ka pipe ipin Títù 3

Wo Títù 3:1 ni o tọ