Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Títù 1:14-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

14. kí àwọn má ṣe fiyè sí ìtàn lásán ti àwọn Júù, àti òfin àwọn ènìyàn tí wọ́n yípadà kúrò nínú òtítọ́.

15. Sí ọlọ́kàn mímọ́, ohun gbogbo ló jẹ́ mímọ́, ṣùgbọ́n àwọn tó ti díbàjẹ́ tí wọ́n kò sí ka ohunkóhun sí mímọ́. Nítòótọ́, ati ọkàn àti ẹ̀rí ọkàn wọn ló ti díbàjẹ́.

16. Wọ́n ń fẹnu sọ wí pé àwọn mọ Ọlọ́run, ṣùgbọ́n wọ́n sẹ́ ẹ nípa ìṣe wọn. Wọ́n díbàjẹ́, aláìgbọ́ràn, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n kò wúlò lọ́nàkọnà ní ti iṣẹ́ rere gbogbo.

Ka pipe ipin Títù 1