Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Títù 1:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó gbọdọ̀ pawọ́n lẹ́nu mọ́, nítorí wí pé wọ́n ń pa agbo Ọlọ́run run, nípaṣẹ̀ àwọn ẹ̀kọ́ tí kò jẹ́ èyí tí wón ń kọ́ni. Èyí ni wọ́n ń ṣe fún ere àìsòdodo.

Ka pipe ipin Títù 1

Wo Títù 1:11 ni o tọ