Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 9:31-33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

31. Ṣùgbọ́n Ísírẹ́lì ti ń lépa òfin òdodo, ọwọ́ wọn kò tẹ òfin òdodo,

32. Nítorí kíni? Nítorí wọn kò wá a nípa ìgbàgbọ́, ṣùgbọ́n bí ẹni pé nípa iṣẹ́ òfin. Nítorí wọn kọsẹ̀ lára òkúta ni;

33. Gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ pé:“Kíyèsi, mo gbé òkúta ìkọ̀sẹ̀àti àpáta tí ó mú wọn subú kalẹ̀ ní Síónì,ẹnikẹ́ni ti ó bá sì gbà a gbọ́, ojú kì yóò tì í.”

Ka pipe ipin Róòmù 9