Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 8:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣíṣe ìgbọ́ran sí ẹ̀mí Mímọ́ ń yọrí sí ìyè àti àlàáfíà. Ṣùgbọ́n títẹ̀lé ara ẹ̀ṣẹ̀ àtijọ́ náà ń yọrí sí ikú.

Ka pipe ipin Róòmù 8

Wo Róòmù 8:6 ni o tọ