Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 8:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ìsòro bá tilẹ̀ ga ju àwọ̀ sánmọ̀ lọ tàbí ní ìsàlẹ̀ omi, ohunkóhun kì yóò lágbára láti yà wá kúrò nínú ìfẹ́ Ọlọ́run, èyí tí Jésù Kírísítì Olúwa fi hàn nígbà tí ó kú fún wa.

Ka pipe ipin Róòmù 8

Wo Róòmù 8:39 ni o tọ