Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 8:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni ẹni náà tí ó lè dá wa lẹ́bi, àwa ẹni tí Ọlọ́run ti yàn fún ara rẹ̀. Ǹjẹ́ Ọlọ́run yóò dá wa lẹ́bi? Bẹ́ẹ̀ kọ́! Òun ni ẹni tí ó dárí jì wá, tí ó sì fi wá sípò tí ó dára lọ́dọ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Róòmù 8

Wo Róòmù 8:33 ni o tọ