Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 8:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti pé lẹ́yìn tí òun ti pè wá wá sọ́dọ̀ ara rẹ̀, ó sọ wá di “aláìjẹ̀bi” lẹ́yìn èyí, ó fi rere Kírísítì kún inú ọkàn wa. Lékè gbogbo rẹ̀, ó fún wa ní ìdúró rere pẹ̀lú rẹ̀, ó sì pinu ògo rẹ̀ fún wa.

Ka pipe ipin Róòmù 8

Wo Róòmù 8:30 ni o tọ