Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 8:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níwọ̀n ìgbà tí a jẹ́ ọmọ rẹ̀, àwa yóò pín nínú dúkìá rẹ̀. Nítorí nǹkan gbogbo tí Ọlọ́run fún Jésù ọmọ rẹ̀ jẹ́ tiwa pẹ̀lú, ṣùgbọ́n bí á bá ní láti pín ògo rẹ̀, a ní láti setan láti pín nínú ìjìyà rẹ̀.

Ka pipe ipin Róòmù 8

Wo Róòmù 8:17 ni o tọ