Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 7:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún àpẹẹrẹ, nípa òfin ní a de obìnrin mọ́ ọkọ rẹ̀ níwọ̀n ìgbà tí ọkọ náà wà láàyè, ṣùgbọ́n bí ọkọ rẹ̀ bá kú, a tú u sílẹ̀ kúrò nínú òfin ìgbéyàwó náà.

Ka pipe ipin Róòmù 7

Wo Róòmù 7:2 ni o tọ