Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 6:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì nígbà tí ẹ̀yin jẹ́ ẹrú ẹ̀ṣẹ̀, ẹ̀yin kò ṣe wàhálà púpọ̀ pẹ̀lú òdodo.

Ka pipe ipin Róòmù 6

Wo Róòmù 6:20 ni o tọ